Má a fún àwo̩n obìnrin tó bímo̩ fún o̩ ní ìwé ìrìnnà fún isé̩ – Anita Brown so̩ fún Davido

Má a fún àwo̩n obìnrin tó bímo̩ fún o̩ ní ìwé ìrìnnà fún isé̩ – Anita Brown so̩ fún Davido

Mary Fágbohùn

Anita Brown, onirawo OnlyFans Amerika eni to so pe oun loyun fun ilumooka olorin Naijiria, Davido, ti jeje pe oun yoo fun awon “obinrin to bimo fun olorin naa ti won n tiraka” ni iwe irinna fun ise.

Anita, eni to ti n fa Davido laso lori ayelujara lati igba to ti fun n loyun, so pe olorin naa kii san owo itoju omo fun awon to ba bimo fun n, o tenumo o pe oun setan lati yi i pada.

Nigba to lo si ori Twitter re ni aaro ojo Eti, o so pe ohun ti Davido se ti n pada bo wa sodo re.

O so pe olorin naa ni awon obinrin mefa ti bimo fun n sugbon o je baba ti ko mo ojuse re gbogbo awon omo naa.

Ninu oro to tele ara won lori Twitter, Anita ko o pe, “Gbogbo awon obinrin to bimo fun o ti won o ri iranlowo kankan gba, kii se emi o, mo de tan ni!

“Maa fun gbogbo awon to bimo ni iwe irinna fun ise, titi di igba ti won ba ri nnkan ti o to si won gba!

“Bii obinrin mefa, WON O RI OWO GBA! Won n tiraka! Won n soro bi oku ikanra! Gbogbo re nitori pe won o le e lo si odo adajo tooto ki won ri oju rere! Iduro to yato! Mo ti DE!”

 

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here