KÉRE Ò !

KÉRE Ò !

Yínká Àlàbí

Kámé̩rà tó ń wo gbogbo Eko lé̩è̩kan náà ti bè̩rè̩ isé̩. E̩ wa mó̩to pè̩lú títè̩lé òfin ìrìnnà Eko.
ÌRÒYÌN ÒWÚRÒ̩ wí tó. Ìgbo̩ràn sàn ju e̩bo̩ rírú lo̩. Fídíò náà rèé nísàlè̩ …