K1 De Ultimate re̩ iye̩ apa re̩, o to̩ro̩ àforíjì

K1 De Ultimate re̩ iye̩ apa re̩ o to̩ro̩ àforíjì

Yínká Àlàbí

Gbaju-gbaja olorin to n lewaju ninu orin Fuji ni orileede yii, Alhaji Wasiu Ayinde.
O ti ni ki gbogbo o̩mo̩ Naijiria lati ori Aare̩ Bo̩la Tinubu, minisita eto irinna ni papako̩ ofurufu, gbogbo awo̩n ti e̩be̩ to̩ si, ki wo̩n jebure̩.
O ni oun kabamo̩ gidi lori ise̩le̩ naa, o ni ki o̩mo̩ Naijiria ma se gbagbe gbogbo awo̩n nnkan daadaa ti oun ti se ge̩ge̩ bi asoju gidi nile̩ yi ati loke okun.
K1 ni omi lasan lo wa ninu ko̩o̩bu naa nitori ailera oun nigba ti oun fe̩ wo̩ baluu kuro ni ilu Abuja.
O ni ju gbogbo re lo, ki gbogbo eniyan forijii oun iru re ko ni sele mo̩.