Home Iléesẹ́ bàlúù Osinbajo sàlàyé ohun tó fa ìjàm̀bá

Iléesẹ́ bàlúù Osinbajo sàlàyé ohun tó fa ìjàm̀bá

Ileese caverton to n se baluu to gbe Ojogbon Yemi Osinbajo ni ki awon omo Naijiria ma se fi oro koro ko awon lorun. Won ni baluu daadaa ni baluu awon. Ko si le tete baje bi o ti wu ki eniyan loo to.
Won ni ohun to sele si eyi to gbe igbakeji Aare lo si ipinle Kogi to tuka nile ni nnkan se pelu oju-ojo ti ko dara. Won ni asiko ti a wa yii, oju ojo ti yato si ti tele. Bayii ile n pe ki o to moo ti o tumo si pe oru gun ju osan lo.
Ileese Caverton ni gbogbo eni to ba maa n fi idaji rin nile gan-an maa mo ohun ti awon n so yii.