Ilé ẹjọ fagilé ìwé ìpẹ̀jọ́ KWAN 1

Ilé ẹjọ fagilé ìwé ìpẹ̀jọ́ KWAN 1

Yínká Àlàbí

Ile ẹjọ giga to fi ikalẹ si ilu Ijẹbu-ode ti fagile iwe enini ti Wasiu Olasunkanmi Ayinde ti gbogbo eniyan mọ si KWAN 1 kọ.
O kọ iwe si ile ẹjọ pe ki wọn da gbogbo ipalẹmọ lori Awujalẹ tuntun duro titi ti awọn afọbajẹ fi maa gbe iwe oun yẹ wo.
Ọjọ Aje, ọjọ kejillelogun osu kejila ọdun yii ni idajọ naa jade.
Ile ẹjọ ni ki gbogbo eto jijẹ Awujale maa tẹ siwaju.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here