Ikú dóró! wó̩n gún Tamilo̩re̩ pa ní Amerika

Ikú dóró! wó̩n gún Tamilo̩re̩ pa ní Amerika

Yínká Àlàbí

O ma se o! O̩fo̩ s̩e̩ ni idile O̩dunsi nigba ti awo̩n osika e̩da kan lo̩ gun un pa si yara re̩ ni o ku o̩la ti wo̩n maa se aye̩ye̩ eto e̩ko̩ no̩o̩si to pari.
O̩mo̩ o̩dun me̩talelogun pere ni Tamilo̩re̩ O̩dunsi. O je̩ o̩mo̩ orileede Naijiria ati ti United Kingdom.
Gbogbo iwadii fihan pe Tamklo̩re̩ o ki n se o̩mo̩ ko̩mo̩. Wo̩n ni onigbagbo̩ ododo ni, ko ki n ke̩gbe̩-ke̩gbe̩. Wo̩n ni o si maa n fe̩ se iranlo̩wo̩ fun eniyan ni gnohno igba.
Ki E̩ledua ba wa ro̩ awo̩n obi re̩ ninu, ki a ma si ri iku o̩do̩ mo̩.