Ikú dóró! Olúbàdàn wàjà

Ikú dóró! Olúbàdàn wàjà

Yínká Àlàbí

Iku wole o̩la, igba a ku laa dere eniyan o sunwon laaye. O̩ba Owolabi O̩lakule̩hin tii s̩e Olubadan ti ile̩ Ibadan re iba agba n re ni e̩ni aado̩run-un o̩dun.
Ki Eledua ba wa de̩le̩ fun e̩ni ire.