Ikú dóró ! Ó yo̩wó̩o̩ òsèré tíátà, Yusuf Olorungbebe láwo
Osere tiata, Yusuf Olorungbebe ti jade laye.
Osere tiata Yoruba naa ni iroyin jade pe o jade laye leyin ti o ja ijakadi pelu aisan kan ti o ko lati fi sile.
Iku re ni gbajumo osere tiata Foluke Daramola fi lede ninu atejade kan lori Instagram re.
O ko o pe, ”A padanu YUSUF OLORUNGBEBE.
”A gba fun Olorun.”