Iko̩ agbábó̩ò̩lù tó lòdì sófin UEFA

Iko̩ agbábó̩ò̩lù tó lòdì sófin UEFA

Yínká Àlàbí

Ò̩sán o̩jo̩ E̩ti oni o̩jo̩ ke̩rin, osu keje, o̩dun 2025 ni ajo̩ UEFA fun awo̩n iko̩ agbabo̩o̩lu kan ni owo itanran pe wo̩n lodi s’ofin ti wo̩n n pe ni FFP (Financial Fair Play).
Ofin yii ni ko ni je̩ ki iko̩ agbabo̩o̩lu kankan wo̩ gbese. Ko ni je̩ ki wo̩n na inakuna ti ko fi ni je̩ ki iko̩ agbabo̩o̩lu be̩e̩ ni o̩jo̩ iwaju.
Awo̩n ti wo̩n maa san owo itanran naa ni – Olympique Lyonnais, Chelsea, Aston Villa, FC Barcelona, ati FC Porto.
Owo itanran wo̩n si je̩-
Chelsea: £17M
Barcelona: £12M
Lyon: £10M
Aston Villa: £9M
Roma: £2.5M