Ìjàm̀bá mọ́tò mú kí ẹbí sún ìgbéyàwó àbúrò Messi síwájú

Ìjàm̀bá mọ́tò mú kí ẹbí sún ìgbéyàwó àbúrò Messi síwájú

Yínká Àlàbí

Maria Sol Messi to jẹ aburo gbaju gbaja agbabọọlu, Lionel Messi, ni ori koyọ nibi ijamba mọto to waye ni Miami to wa ni orileede Amerika.
Ijamba mọto yii pọ de bi wi pe wọn ti bẹrẹ si ni se isẹ abẹ fun un. Ara rẹ ti n ya, ireti si wa sugbọn loju ẹsẹ ni gbogbo ẹbi ti fori kori pe igbeyawo rẹ to yẹ ki o waye ni Rosario ti Argentina ni ọjọ kẹta, osu kin-in-ni ọdun 2026 ni wọn ti gbe fo titi ti ara rẹ fi maa ya.
Angel de Brito, to jẹ akoroyin ni ori telifisọn Argentina lo kọkọ jẹrii si ijamba naa.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here