Ìbejì làǹti-làǹti wọlé tọ Adekunle Gold àti ìyàwó rẹ̀
Ìròyìn òwúrọ̀
Gbaju-gbaja olorin, Adekunle kosoko sugbọn ti gbogbo eniyan mọ si Adekunle Gold ati iyawo rẹ Simi ki awọn ọmọ tuntun jojolo kaabo sile wọn.
Ọdun 2019 ni awọn mejeeji ṣe igbeyawo ti Eledua si fi obinrin lanti-lanti ta wọn lọrẹ.
Lẹyin Adejare ti o waye ni ọdun 2020 ni wọn ti n woju Ọlọrun ki Baba to fi meji ta wọn lọrẹ dipo ẹyọkan ti wọn n gbadura fun lojoojumọ.
Ori ẹrọ ayelujara snapchat wọn ti ẹri awọn ibeji naa ti mulẹ.









