Hilda Baci setán láti se agbada ńlá ìresì fún gbogbo ayé je̩
Mary Fágbohùn
Gbajumo olounje ayo, Hilda Baci tun gbara tuntun jade ni bi se n gbiyanju lati seto fun ase nla eleyii to ti n lo kaakiri lori ayelujara.
Baci fe se ape iresi to tobi julo ni agbaye ni Ojo Kejila osu kesan an, odun 2025.
Ase naa, to pe ni Gino World Jollof Festival, yoo waye ni gbagede Muri Okunola Park nilu Eko, o si seleri pe yoo je ajoyo ounje ile, orin ati asa Afrika.
O kowe pe, “Iwon mita mefa ni fife. Iwon mita mefa ni giga. Ni Ojo Kejila Osu Kesan, kajo ko itan papo. Nitori kinni iresi aladun laisi eyin eniyan mi lati oun pelu”
Ajoyo naa ni awon onirunru olorin yoo ti maa sere, o si sile fun gbogbo eniyan lati wole.
Ife Baci tooto fun iresi aladun koja ti sise lo; o n gboro lati pin pataki ounje to ba asa mu ati lati ko awon eniyan jo.
Pelu akosile re ninu iwe Guinness World Record tele bii Alase to dana to pe ju lagbaye, Baci ni aridaju wa pe lako loun wa bi ibon lati fi iresi yii ko itan tuntun miran.