Golí Super Eagles Nwabali pàdánù òbí méjèèjì

Golí Super Eagles Nwabali pàdánù òbí méjèèjì

Ìròyìn òwúrọ̀

Oni ọjọ Abamẹta, osu kin-in-ni, ọdun yii ni iroyin nipa bi Goli akọkọ fun ikọ super Eagles, Stanley Nwabali se padanu mama rẹ lẹyin aisan ranpẹ.
Osu meji sẹyin ni baba Goli yii dagbere faye, Nwabali ni ọrọ naa toju su oun gẹgẹ bi o se salaye ni oju opo ayelujara Facebook rẹ.
Super Eagles si ni ifagafaga pẹlu Mambas ti Mozambique ni ọtunla yii ninu AFCON 2025 to n lọ lọwọ ni orileede Morocco.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here