FIFA Club World Cup 2025: Àwọn akọni ku mẹ́rin

FIFA Club World Cup 2025: Àwọn akọni ku mẹ́rin

Yínká Àlàbí

Idije to kẹyin si asekagba maa waye ni ọla ọjọ kẹjọ ati ọtunla ọjọ kẹsan-an, osu keje ọdun yii ni papa isere Metlife to wa ni East Rutherford, New Jersey, USA.
Asekagba gan-an maa waye ni ọjọ kẹtala osu yii kan naa ni papa isere kan naa. Awọn ikọ agbabọọlu mẹrin to ku naa ni – Fluminense, Chelsea, PSG ati Real Madrid.
Ikọ agbabọọlu Fluminense lo maa kọju Chelsea nigba ti PSG maa gbena woju Real Madrid.