Home Egúngún Èkó ń sẹ̀wọ̀n

Egúngún Èkó ń sẹ̀wọ̀n

Ọwọ awon olopaa Agege ti te awon to n fi egungun lu jibiti ni Agege, ipinle Eko. Ni igba ti oga olopaa tuntun Edgar Imohimi de si Eko lo ti koko ke gbajare si gbogbo onile ati alejo pe “ikoko ti oun ko ni gba omi, ko tun gba eyin”.

Imohimi ni ko si si aaye fun iwa jibiti mo ni ipile Eko, eyi lo mu ki o de panpe kaakiri ipinle Eko ti o si mu awon onijibiti egungun yii. O ni ko si ewu ninu ki eleegun o se eegun re, sugbon gbogbo nnkan ni o ni asiko re. O ni, awon ara ilu lo koko fi ejo awon egungun yii sun pe bi won se  fi jibiti oogun gba owo ni won n ko oja lori igba, ni eyi to lodi si ofin orileede yii.

E wo fidio isale yii, ki e wo bi awon onijibiti se n ba asa je.