EFCC fọwọ́ sìnkún òfin mú Malami nítorí owó bíi ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta dọ́là

EFCC fọwọ́ sìnkún òfin mú Malami nítorí owó bíi ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta dọ́là
Yínká Àlàbí
Ajọ EFCC ti fi ẹ̀sùn dí Malami mọ́lẹ̀ pé kó lọ sí orílẹ̀-èdè míì, wọ́n sì gba iwe-irinna rẹ̀. Ọ̀kan lára àwọn àdéhùn wọn ni pé kó máa lọ sí ọ́fíìsì EFCC ní Abuja lojoojúmọ́ láti Oṣù Kejìlá ọjọ́ kin-in-ni titi di ọjọ kọkanlelọgbọn osu kejila odun yii.
Ajọ EFCC náà sọ pé ìwádìí pọ̀ ti awọn jọ maa se, ó sì ní òpò ìwé tí Malami ní láti ṣàlàyé, pàápàá jùlọ nípa ibi tí owo to fẹrẹ to ẹẹdẹgbẹta miliọnu owo dọla ($490m) owo ti orileede gba lọwọ Abacha.
EFCC sọ pé awọ́n kò ṣàlàyé pé ó ji owó, ṣùgbọ́n pé ó ní láti ṣalaye bi owo naa se rin. Wọ́n tún sọ pé wọn kò ní bá ẹnikẹ́ni ja tabi rojọ rẹpẹtẹ sugbọn awẹn maa jẹ ki gbogbo aye mọ ohun to sẹlẹ lẹyin iwadii awọn.
Gẹgẹ bi akọsilẹ olori idajọ tẹlẹ ni orileede yii, Alagba Malami, o ni ọrọ oselu lasan ni wọn gbe wọ ọrọ naa nitori pe oun ko lẹbọ lẹru rara.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here