Ẹ f’òpin sí Indomine ní jíjẹ – NAFDAC

Ẹ f’òpin sí Indomine ní jíjẹ – NAFDAC

Yínká Àlàbí

Ajọ ijọba apapọ orileede Naijiria (National Agency for Food and Drugs Administration and Control) NAFDAC to n se amojuto ounjẹ ati oogun ti se ikilọ fun gbogbo ọmọ Naijiria lati fopin si Indomine jijẹ lasiko yii.
Wọn ṣe ikilọ pataki yii lati ara ayewo kan to waye ni orileede France nipa ounjẹ to yara se, yara ra ati yara lati jẹ ti a n pe ni Indomine .
NAFDAC ni awọn to n see ko salaye osuwọn miliiki ati ẹyin inu rẹ, ni eyi to le se akoba fun awọn eniyan kan gẹgẹ bi ẹya ara wọn se ri.
Ajọ NAFDAC wa ni ki gbogbo ọmọ Naijiria si ni suuru na ti iya sọtọ fi maa waye.
Eyi ti aleebu wa lara rẹ gan an ni “Indomie brand Noodles Vegetable Flavour product.”
Ajọ NAFDAC ti da awọn osisẹ wọn sita lati le maa wa ibi ti awọn Indomine yii wa, koda wọn fi nọmba wọn naa sita fun awọn ara ilu to ba kefin iru Indomine naa – 0800-162-3322.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here