E̩ni tí kò bá fé̩ s’o̩dún látìmó̩lé, kó má s̩e bá wo̩n yin báńgà – E̩gbe̩tokun
Yínká Àlàbí
Kére o! Kéku ilé ó gbó̩, kó so̩ fún t’oko. Kí àdán o gbo̩, kó ro f’óòbè. Ní àsìkò o̩dún yìí. Kò si ààyè fún báńgà yíyìn.
Ò̩gá o̩ló̩pàá pátápátá ní orílèèdè yìí, Ò̩gbé̩ni Kayo̩de E̩gbe̩tokun ti ni o̩mo̩ ti ko ba fe̩nlo̩ so̩dun ni atimo̩le, ko ma se dasa yiyin nnkankan nitori aabo ilu.
O̩ga o̩lo̩paa ni awo̩n e̩s̩o̩ oun gbo̩do̩ mo̩ igba ti awo̩n e̩ni ibi ba de.
Ó ní tí O̩ló̩run ba n só̩ wa, kí awa naa maa gbìyànjú láti s̩o̩ ara wa.
E̩ gbó̩ Ò̩gá o̩ló̩pàá fúnra yín nísàlè̩..









