ÌRÒYÌN L'ÁPAPỌ̀ÒṢELÙ E̩ja ńlá lo̩ lómi, Buhari re ibi àgbà ń rè By iroyinowuro - July 13, 2025 FacebookTwitterPinterestWhatsApp E̩ja ńlá lo̩ lómi, Buhari re ibi àgbà ń rè Yínká Àlàbí Iroyin yajoyajo gbee laipe̩ yii pe Aare̩ ana, Muhamnadu Buhari dagbare faye ni ile iwosan kan ni ilu London. Ki Eledua de̩le̩ f’e̩ni ire.