Davido se ‘tuale’ fún Sanwo-Olu 

Davido
Gbajugbaja akorin, Davido, ti kan saara si Gomina Ipinle Eko, Alagba Babajide Sanwo-Olu.
O se eyi lasiko to ki i ku oriire pipe ogota odun loke eepe.
Ninu fidio kan, Davido ni alaseyori gomina ni Sanwo-Olu je.
O ni gbogbo nnkan ribiribi ti o n gbe se ni ilu Eko ni araye n ri.
O wa ro awon ololufe re ki won ba oun da muso fun un, tori pe oun nifee gomina naa pupo
Gomina Babajide Sanwo-Olu