LÁGBO ÀRÍYÁ
Ìtọpinpin àwọn oníròyìn ló jẹ́ kí wọ́n rí Profeṣsor Peller pa – Iyawo opidan naa
Alhaja Silifa Abiola Peller, eni to je iyawo Oloogbe Abiola Peller, ti se alaye bi awon aalagbapa (hired killers) se ri bale oun pa. Won ni ‘E mu u, e ki I, eranko bee ko ni oore.’ Opidan ti gbogbo aye mo si Professor Peller naa ki se eni kan…
Read More »Àìlera kan bá mi làsìkò tí mo gbé IJÓ YÓYÒ jáde – Kollington Ayinla
Osere fuji pataki, Alhaji Kollington Ayinla, ti so asiri kan lori orin re kan to laluja, iyen IJO YOYO. Opo eniyan lo gba pe orin naa lo gbayi julo, ti o si je pe o si maa n dun leti di oni olonii. Bakan naa ni fidio orin naa lagboro,…
Read More »Mo ti ká Ajimobi pè̩lú obìnrin mìíràn lé̩è̩mejì – Florence Ajimobi
Mo ti ká Ajimobi pè̩lú obìnrin mìíràn lé̩è̩mejì – Florence Ajimobi Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínka Àlàbí Ko si ibi ti ese ko si, eyi lo maa n mu ki awon agba Yoruba maa so pe “eni eegun n le ki o maa roju nitori pe bi o se n re…
Read More »Toyin Abraham ò tíì ṣe ìgbéyàwó – Manager re.
Manija Toyin Abraham, Samuel Olatunji ti soro nipa igbeyawo Toyin. Samuel ni aworan Toyin ti o wa kaakiri kii se aworan igbeyawo, o ni aworan mo mi mo e lasan ni, ti o waye ni July 14. O ni mo mi mo e nikan ni won se pe Toyin…
Read More »Toyin Abraham to ṣe ìgbéyàwó.
Gbajumo osere Toyin Abraham se mo mi mo e pelu baba omo re ti o si je onsere onitiata Yoruba, Kolawole Ajeyemi ni ojo Thursday July 4. Won se mo mi mo e naa ni ile Toyin, awon ti o si wa ni ibe ni Kolawole Ajeyemi, Yeyeluwa Odebunmi, Honorable…
Read More »Àwòrán Aláàfin Ọ̀yọ́ àti àwọn ìyàwó rè.
Aworan Alaafin Oyo ati awon iyawi re nigba ti won se ayeye Eid-Mubarak in ipinle Oyo ni ana August 12.
Read More »Genevieve gbé àwòrán ara rẹ̀ sí orí Instagram.
Gbajumo osere onitiata, Genevieve Nnaji, gbe aworan re si ori instagram, aworan naa si pe opolopo akiyesi awon eeyan si odo re.
Read More »Kò wùnmí láti fi oyún mí pamọ́ – Wunmi Toriola.
Gbajumo osere onitiata Yoruba, Wunmi Toriola ti kilo fun awon ti n gba nimoran pe ki o ye gbe oyun re sita fun araye ri pe ki won fi oun sile, pe won n fa nnkan odi si ori paagi oun. Gege bi o se so, o ni oun fe…
Read More »Orí Facebook ni mo ti pàdé ọkọ mí – Simi.
Gbajumo akorin omo Naijiria, Simi ti o je aya gbajumo akorin Adekunle Gold, ti salaye ninu iforowanilenwo bi oun se pade oko oun, bi o tile je pe bonkele ni won fi ibasepo won se. Ninu ifoworowanilenuwo ti o ni pelu Ndani tv ni o ti salaye pe ori Facebook…
Read More »Ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Dolapo Osinbajo, iyawo Igbákejì Ààrẹ Yemi, ti pe omo odun mejilelaadota lonii July 15. O gbe aworan ojo ibi re akoko si ori instagram, o si n dupe lowo olorun fun ojo ibi naa. O ni: Mo dupe lowo olorun fun ojo ibi miiran . Ojo ibinmi akoko A f’ope…
Read More »