June 26, 2022
Trending Now
  •    IROYIN OWURO TI OSE yi...

  •    Dayo Amusa n beere pe ta lo maa n gbadun ibalo...

  •    Akowe ACOMRON lu olokada pa pelu oruka aluwo...

  •    IROYIN OWURO TI OSE YI...

  •    Pàtàkì orúkọ nínú ọfọ̀,ògèdè àti àásán...

  •    ‘Arun ogbe inu (ulcer) lo mu Ogogo nigba...

  •    NURTW ń gbéná wojú Fayose...

  •    Lai Mohammed gbona eburu yo si Saraki ni Kwara...

  •    Idi ti mo fi se ere ibalopo okunrin ati okunri...

  •    Eni kan lo mo, awon osere ti adanwo nla ba ni ...

  •    Idi ti n ko fi se fiimu mo – Toyosi Arigbabuwo...

  •    Orúkọ tí ó jẹ mọ́ ìdílé...

Ohun Omo Oduduwa

  • Ohun Omo Oduduwa
  • Ẹ BÁ WA DÉLÉ
  • ỌRỌ̀-AJÉ
  • Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ
  • LÁGBO ÀRÍYÁ
  • ÀRÒJINLẸ̀
  • ÀṢÀ ÀTI ÌṢE
  • òpómúléró
  • ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
  • ÌPOLÓWÓ ỌJÀ
Home ÀRÒJINLẸ̀

ÀRÒJINLẸ̀

  • Ojúmọ́ kan, oògùn kan

    March 27, 2020
    0 518
    ÀKỌ̀TUN

    Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko leta si Aare to maa dogun dode. Lenu odun yii…

    Read More »
  • Ọ̀nà Jìbìtì

    March 18, 2020
    0 324
    ÀKỌ̀TUN

    Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo…

    Read More »
  • Àbá Àseyorí 2020

    January 7, 2020
    0 447
    ÀKỌ̀TUN

    Gbogbo eyin alarojinle, e ku ojo meta. Eledua ko ni je ki a su ara wa. Awa ti a foju wina ipenija ilu yii naa lo maa je oro ilu naa lase Edumare. Bi ere bi awada, odun 2019 keru nile, o maa di oro itan laarin wakati meloo kan…

    Read More »
  • Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná

    October 29, 2019
    0 716
    ÀRÒJINLẸ̀

    Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná Lati owo Yinka Alabi Iya agbalagba ti ko din ni aadorin odun lo lo roo pin si ofiisi ajo apina-ka (IBEDC) Ibadan Electricity Distribution Company to fi ikale si ilu Osogbo. Mama yii di awon nnkan to le nilo ti…

    Read More »
  • Àsírí Òkété

    October 18, 2019
    0 1,030
    ÀKỌ̀TUN

    ÒKÉTÉ. ___ Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀. Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò le rí èrùpẹ̀ lẹ́nu isà òkété, bí…

    Read More »
  • Ara kò rokùn…

    July 24, 2019
    0 508
    ÀKỌ̀TUN

    Eyin alarojinle, e ma ku ojo meta. Ilu lilu toni o ki n se ilu alujo rara. Eto aabo Orileede yii ni o n ko gbogbo wa lominu. Eni to ba si ni oro naa ko kan oun, boya lo mo pe, nigba to kan oun tan, o tun se…

    Read More »
  • Ìjà tí wáyé ní pápá ọkọ̀ -òfuurufú ti Abuja.

    Lola July 9, 2019
    0 448
    ÀRÒJINLẸ̀

    Ija ti be sile ni Nnamdi Azikiwe Airport ni Abuja. Gege bi iroyin se so, a gbo pe iya naa waye laaatin awon ti won fe wo oro ofurufu ti Airpeace, awon ti n lo si Enugu atinawon ti n lo si Eko n ja si eni ti o ma…

    Read More »
  • Arábìnrin ti fi ìyà jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ nítorí ó ké pe ìrànlọ́wọ́.

    Lola July 4, 2019
    0 1,265
    ÀRÒJINLẸ̀

    Laaarin awuyewuye ti n lo lowo nipa ifipabalopo, orisirisi obinrin lo ti n so awon nnkan ti oju won ti ri seyin nipa ifipabalopo. Bee ni a si ri awon obinrin miiran ti won ko ni aanu obinrin bi egebe won. Arabinrin kan, Agatha Ayerite, ti so lori Facebook bi…

    Read More »
  • Ìyá ti fi oògùn p’ẹ̀fọn(sniper) pa ọmọ rẹ̀.

    Lola July 4, 2019
    0 359

    Arakunrin kan @aproko_doctor ti so lori twitter bi iya se fi oogun p’efon si ori omo re lati pa kokoro ti o wa ni ori re, ti o si gba emi omo naa. O ni “ mo sese gbo itan ti o banileru nipa iya ti o fi oogun p’efon…

    Read More »
  • Bàbá tí ọmọ rẹ̀ pa fún ogún ọdún nítorí wárápá.

    Lola July 4, 2019
    0 842
    ÀRÒJINLẸ̀

      Arakunrin omo odun metalelogun, ti o n je Basty Abass, ti wa ni atimole fun ogun odun ni Nkwanta south ti Oti region, ni orile-ede Ghana, ti a gbo pe baba re ti mole nitori o ni warapa. A gbo lati oju feresi nikan ni Abass ti ma n…

    Read More »
Next page

DON'T MISS

IROYIN OWURO TI OSE yi

iroyinowuro@gmail.com
June 6, 2017

Dayo Amusa n beere pe ta lo maa n gbadun ibalopo ju larin okunrin ati obinrin

July 9, 2018

Akowe ACOMRON lu olokada pa pelu oruka aluwo

July 6, 2018

IROYIN OWURO TI OSE YI

February 19, 2018

Pàtàkì orúkọ nínú ọfọ̀,ògèdè àti àásán

iroyinowuro@gmail.com
July 9, 2017

YOU MIGHT LIKE

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

10 hours ago

Agbẹjọ́rọ́ tó wọ asọ òòsà ilé rẹ̀ lọ ilé ẹjọ́ k’ẹ́rẹ̀ bá isẹ́ amòfin – MURIC

22 hours ago

Portable olórin, Zaa zuh ṣègbéyàwó pẹ̀lú ìyá ọmọ rẹ̀

3 days ago

EDITOR’S PICKS

  • July 30, 2017

    Ìdánrawò

  • July 29, 2017

    Àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun sì ń nífẹ̀ẹ́ ẹbí mi – Ademola Adeleke

  • August 7, 2017

    Ẹ jọ̀wọ́ o, ta ló bá wa gbúròó Àgbákò?

  • August 8, 2017

    Ìyàwó Tuface ní òun kò ní bímọ mọ́

POPULAR POSTS

Orisirisi

IROYIN OWURO TI OSE yi

Orisirisi

Dayo Amusa n beere pe ta lo maa n gbadun ibalopo ju larin okunrin ati obinrin

iroyin

Akowe ACOMRON lu olokada pa pelu oruka aluwo

© Copyright 2019 - Iroyin Owuro Powered by Oriki Technologies
  • Latest News
  • Advertisement
  • Privacy
  • Contact