Block 44 - Timeline
- Jul 20193 July
“Mo ti ṣiṣẹ́ rí láàárín àwọn agbèrò àti oní panṣágà” – ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo.
Iyawo igbakeji aare Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo, ti so pe oun ti sise ri laaarin awon agbe p ati oni pansaga ni Eko. O…
- Jun 201912 June
Arábìnrin tó rẹwà yìí ń fi ìlà ojú rè hàn.
Arabinri yii n fi igberaga ati owo lati fi ila oju re han. O ni oun ni obinrin to dara ju to ni ila…
- Jul 20198 July
Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.
Aworan igbeyawo baba ati iya agbalagba yii waye ni ipinle Zaria, igbeyawo won naa si fun olopopo awon eeyan ni ireti. Arakunrin kan ti…
- 11 July
Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.
Won ti pa akekoo oniwe eri Phd ti o n je Thomas Orhionsefe Ewansiha ni Malaysia. Thomas si je olomo meji. Oga imigiráṣọ̀n ni…
- Jun 201925 June
Ilé ìjọsìn kan ti fi àwọn nǹkan tí ó ma gbé àwọn wọ ọ̀run àpáàdì.
Ile ijosin kan ti fi aworan nnkan ti o ma gbe awon eeyan wo orun apaadi han.
- 7 June
Ìyàwó onítíátà Kunle Afolayan ti sọ pé, ìṣe abẹ ni oun fi bí àwọn ọmọ òun mẹ́rin.
Iyawo Kunle Afolayan, Desola Afolayan ti salaye pe oun gbiyanju ati yo oyun oun kerin. Nigba ti o ki omo re abigbeyin, Yiyenitemi, fun…
- 29 June
Pásítọ̀ Tony Rapu ti ṣàlàyé ìdí tí àwọn olórí o ṣe ní ìgboyà láti ṣe nǹkan to tọ lórí ọ̀rọ̀ ìfipábálòpọ̀.
Laaarin gbogbo rògbòdìyàn ti n lo lori afefe nipa esun ti won fi kan pasito Biodun Fatoyinbo, eniyan olorun miiran, Pasito Tony Rapu ti…
- Jul 201912 July
Ìṣe ẹlẹ́yàmẹyà ni láti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wón lóyún kúrò ní ilé ìwé kí wón sì fi àwọn ọkùnrin tó fún wọn lóyún sílè – Obìnrin àkọ́kọ́ Ìpínlẹ̀ Ekiti.
Aya Gomina ipinle Ekiti, Arabinrin Bisi Fayemi, ti so pe ise eleyameya ni lati ma a le awon obinrin akekoo ti won loyun kuro…
- Jun 201913 June
ìdíje FIFA Women World Cup: Naijiria na Korea 2 – 0.
Awon agbaboolu obinrin ti orile-ede Naijiria ti ni anfaani lati koja si ipele to n bo ninu FIFA Women World Cup ti n lo…
- Mar 202016 March
Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩
Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩ Iroyin lati owo Akinwale Taophic Atamatase fun orileede wa Nigeria nigba kan ri, eni ti o se gudugudu…
- Jun 201926 June
“Ẹ̀yin Òǹṣèré, ìgbà tí yàtọ̀, ẹ ní láti ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn fáànù yín” – Don Jazzy.
Ni aaro yi, Don Jazzy n salaye bi ibasepo pelu awon faanu awon akorin se pataki si won. O ni “Eyin akorin, igba ti…
- 28 June
Pásítọ̀ COZA, Biodun Fatoyinbo ti fi èsì sí e ẹ̀sùn tí ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kàn án pé ó fi ipá bá òun ní àjọṣepò.
Pasito COZA, Biodun Fatoyinbo, ti ni oun o mo nnkankan nipa esun ti iyawo Timi Dakolo, Busola fi kan oun. Ninu gbolohun ti o…