Block 40
“Mo ti ṣiṣẹ́ rí láàárín àwọn agbèrò àti oní panṣágà” – ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo.
Iyawo igbakeji aare Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo, ti so pe oun ti sise ri laaarin awon agbe p ati oni pansaga ni Eko. O so eyi i Anti-Substance-Abuse Programme lati se International Day Against Drug Abuse…
Read More »Arábìnrin tó rẹwà yìí ń fi ìlà ojú rè hàn.
Arabinri yii n fi igberaga ati owo lati fi ila oju re han. O ni oun ni obinrin to dara ju to ni ila to rewa ju, oun o si tiju lati fi han.
Read More »Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.
Aworan igbeyawo baba ati iya agbalagba yii waye ni ipinle Zaria, igbeyawo won naa si fun olopopo awon eeyan ni ireti. Arakunrin kan ti n jd Chinecherem Ebubechi lo gbe aworan naa si ori Facebook, oko…
Read More »Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.
Won ti pa akekoo oniwe eri Phd ti o n je Thomas Orhionsefe Ewansiha ni Malaysia. Thomas si je olomo meji. Oga imigiráṣọ̀n ni won pa a si leyin fi awon imigirason mu fun esun ti…
Read More »Ilé ìjọsìn kan ti fi àwọn nǹkan tí ó ma gbé àwọn wọ ọ̀run àpáàdì.
Ile ijosin kan ti fi aworan nnkan ti o ma gbe awon eeyan wo orun apaadi han.
Read More »