Block 36
“Mo ti ṣiṣẹ́ rí láàárín àwọn agbèrò àti oní panṣágà” – ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo.
Iyawo igbakeji aare Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo, ti so pe oun ti sise ri laaarin awon agbe p ati oni pansaga ni Eko. O so eyi i Anti-Substance-Abuse Programme lati se International Day Against Drug Abuse…
Read More »Arábìnrin tó rẹwà yìí ń fi ìlà ojú rè hàn.
Arabinri yii n fi igberaga ati owo lati fi ila oju re han. O ni oun ni obinrin to dara ju to ni ila to rewa ju, oun o si tiju lati fi han.
Read More »Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.
Aworan igbeyawo baba ati iya agbalagba yii waye ni ipinle Zaria, igbeyawo won naa si fun olopopo awon eeyan ni ireti. Arakunrin kan ti n jd Chinecherem Ebubechi lo gbe aworan naa si ori Facebook, oko…
Read More »Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.
Won ti pa akekoo oniwe eri Phd ti o n je Thomas Orhionsefe Ewansiha ni Malaysia. Thomas si je olomo meji. Oga imigiráṣọ̀n ni won pa a si leyin fi awon imigirason mu fun esun ti…
Read More »Ilé ìjọsìn kan ti fi àwọn nǹkan tí ó ma gbé àwọn wọ ọ̀run àpáàdì.
Ile ijosin kan ti fi aworan nnkan ti o ma gbe awon eeyan wo orun apaadi han.
Read More »Ìyàwó onítíátà Kunle Afolayan ti sọ pé, ìṣe abẹ ni oun fi bí àwọn ọmọ òun mẹ́rin.
Iyawo Kunle Afolayan, Desola Afolayan ti salaye pe oun gbiyanju ati yo oyun oun kerin. Nigba ti o ki omo re abigbeyin, Yiyenitemi, fun ojo ibi re. O ni ise abe ni oun fi bi awon…
Read More »Pásítọ̀ Tony Rapu ti ṣàlàyé ìdí tí àwọn olórí o ṣe ní ìgboyà láti ṣe nǹkan to tọ lórí ọ̀rọ̀ ìfipábálòpọ̀.
Laaarin gbogbo rògbòdìyàn ti n lo lori afefe nipa esun ti won fi kan pasito Biodun Fatoyinbo, eniyan olorun miiran, Pasito Tony Rapu ti so ana ti awon eeyan le gba lati mu iru isele bayii.…
Read More »Ìṣe ẹlẹ́yàmẹyà ni láti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wón lóyún kúrò ní ilé ìwé kí wón sì fi àwọn ọkùnrin tó fún wọn lóyún sílè – Obìnrin àkọ́kọ́ Ìpínlẹ̀ Ekiti.
Aya Gomina ipinle Ekiti, Arabinrin Bisi Fayemi, ti so pe ise eleyameya ni lati ma a le awon obinrin akekoo ti won loyun kuro ni ile iwe ki won si fi awon okunrin ti won fun…
Read More »ìdíje FIFA Women World Cup: Naijiria na Korea 2 – 0.
Awon agbaboolu obinrin ti orile-ede Naijiria ti ni anfaani lati koja si ipele to n bo ninu FIFA Women World Cup ti n lo lowo leyin ti won na South Korea ni 2 – 0, Agbaboolu…
Read More »Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩
Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩ Iroyin lati owo Akinwale Taophic Atamatase fun orileede wa Nigeria nigba kan ri, eni ti o se gudugudu meje ati yaaya mefa ninu idije ife eye ile adulawo ti won…
Read More »“Ẹ̀yin Òǹṣèré, ìgbà tí yàtọ̀, ẹ ní láti ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn fáànù yín” – Don Jazzy.
Ni aaro yi, Don Jazzy n salaye bi ibasepo pelu awon faanu awon akorin se pataki si won. O ni “Eyin akorin, igba ti yato o. Oro Chris brown yii to lati he ki e mo…
Read More »Pásítọ̀ COZA, Biodun Fatoyinbo ti fi èsì sí e ẹ̀sùn tí ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kàn án pé ó fi ipá bá òun ní àjọṣepò.
Pasito COZA, Biodun Fatoyinbo, ti ni oun o mo nnkankan nipa esun ti iyawo Timi Dakolo, Busola fi kan oun. Ninu gbolohun ti o fi kale ni irole yii, Fatoyinbo ni oun o fi ipa bi…
Read More »