Block 33
Arábìnrin tó rẹwà yìí ń fi ìlà ojú rè hàn.
Arabinri yii n fi igberaga ati owo lati fi ila oju re han. O…
Bàbá ọdún mẹ́tàlélàádọ́ta tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú màmá ọdún mẹ́talélọ́gọ́ta.
Aworan igbeyawo baba ati iya agbalagba yii waye ni ipinle Zaria, igbeyawo won naa…
Wọ́n ti pa akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ Nàìjíríà oní ìwé ẹ̀rí Phd ni àgọ́ imigiráṣọ̀n ní orílẹ̀ èdè Malaysia.
Won ti pa akekoo oniwe eri Phd ti o n je Thomas Orhionsefe Ewansiha…
Ilé ìjọsìn kan ti fi àwọn nǹkan tí ó ma gbé àwọn wọ ọ̀run àpáàdì.
Ile ijosin kan ti fi aworan nnkan ti o ma gbe awon eeyan wo…
Ìyàwó onítíátà Kunle Afolayan ti sọ pé, ìṣe abẹ ni oun fi bí àwọn ọmọ òun mẹ́rin.
Iyawo Kunle Afolayan, Desola Afolayan ti salaye pe oun gbiyanju ati yo oyun oun…
Pásítọ̀ Tony Rapu ti ṣàlàyé ìdí tí àwọn olórí o ṣe ní ìgboyà láti ṣe nǹkan to tọ lórí ọ̀rọ̀ ìfipábálòpọ̀.
Laaarin gbogbo rògbòdìyàn ti n lo lori afefe nipa esun ti won fi kan…
Ìṣe ẹlẹ́yàmẹyà ni láti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wón lóyún kúrò ní ilé ìwé kí wón sì fi àwọn ọkùnrin tó fún wọn lóyún sílè – Obìnrin àkọ́kọ́ Ìpínlẹ̀ Ekiti.
Aya Gomina ipinle Ekiti, Arabinrin Bisi Fayemi, ti so pe ise eleyameya ni lati…
ìdíje FIFA Women World Cup: Naijiria na Korea 2 – 0.
Awon agbaboolu obinrin ti orile-ede Naijiria ti ni anfaani lati koja si ipele to…
Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩
Ighalo so̩ àwo̩n e̩lé̩gàn di òpùró̩ Iroyin lati owo Akinwale Taophic Atamatase fun orileede…
“Ẹ̀yin Òǹṣèré, ìgbà tí yàtọ̀, ẹ ní láti ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn fáànù yín” – Don Jazzy.
Ni aaro yi, Don Jazzy n salaye bi ibasepo pelu awon faanu awon akorin…
Pásítọ̀ COZA, Biodun Fatoyinbo ti fi èsì sí e ẹ̀sùn tí ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kàn án pé ó fi ipá bá òun ní àjọṣepò.
Pasito COZA, Biodun Fatoyinbo, ti ni oun o mo nnkankan nipa esun ti iyawo…