Ayra Starr kéde Wizkid bí o̩ba orin takasufe
Mary Fágbohùn
Olorin Naijiria Ayra Starr ti kede akegbe re olugbafe eye Grammy, Wizkid, Bibbia orin takasufe.
Loooto ni awuyewuye ti n ja raninranin lori ayelujara bi i ojo meta lori talagba orin takasufe laarin Wizkid, Davido, ati Burna Boy, ti a tun n pe ni “Big 3.”
Lasiko to n soro ninu iforowero pelu Complex laipe yi, Ayra Starr fi igboya kede Wizkid bi oba ninu eya orin naa.
O salaye pe oun pinnu lati ba olorin Starboy sise po ninu orin‘Gimme Dat’ nitori ko si elomiran to n se “orin takasufe to fanimora” bii tire.
“
“Ko si elomiran to duro deede fun orin naa [‘Gimme Dat’] ayaafi Wizkid. Koda iro re bii ti aloyinlohun, ilana ese orin naa farajo ti Wizkid; o dabii orin takasufe to joju lopo. Gbogbo eniyan si mo pe Wizkid lona orin takasufe to fanimora,” ge̩ge̩ bi o se salaye.