Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ AAUA s’àjọ̀dún ìparí ẹ́kọ́ wọn.

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ AAUA s’àjọ̀dún ìparí ẹ́kọ́ wọn.

Gbọ́láhàn Quseem

Sé wọ́n ní b’ọ́dún bá dùn, ó di dandan k’á r’ohun àjọ̀dún. Bẹ́ẹ̀ gan-an lọ̀rọ̀ ní bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ile-ẹ̀kọ́ Adékúnlé Ajásin, ẹ̀ka t’Ibàdàn t’ó kalẹ̀ s’ágbègbè Ọ̀rẹ́méjì ti n se àjoyọ̀ ìparí ẹ̀kọ́ wọn t’ó wáyé n’ilé-ẹ̀kọ́ ọ̀un l’ọ́jọ́ Àbámẹ́ta ọjọ́ kẹrínlélógún osù karùn-ún ọdún 2025.

Nigba ti o n sọrọ nibi ayẹyẹ ikẹkọjade ọun, Olukọ agba kan t’o tun jẹ alakoso eto igbaniwọle fun Mufutau Lanihun College of Education, Arakunrin Sirajudeen Adebolu t’o s’oju fun ọga ile-ẹkọ ọun, gba awọn akẹkọọ n’iyanju lati ma tẹsiwaju ninu daadaa ti wọn ti wọn n se bọ, ki wọn le se aseyọri t’o gbọn-n-gbọn. Ọga agba naa tun mu wa s’iranti awọn akẹkọọ pe l’ọdun 2020/2021 ati 2021/2022 t’awọn akẹkọọ ọun bẹrẹ ẹkọ wọn n se lo dabi pe ko ni tan mọ.

S’aaju nibi ọrọ ti ẹ, Aarẹ awọn akẹkọọ ile-ẹkọ naa, Arakunrin Ajibade Owoyẹmi lsiaq dupẹ fun ọba adẹda eleyi t’o jẹ ki eto ọun kẹsẹjari. Bakannaa, lo tun dupẹ lọwọ Ọlọhun fun aseyọri wọn nibi ẹka eto ẹkọ ti olukuku wọn yan laayo.

Ọpọ awọn akẹkọọ lo gba amiẹyẹ oriṣiriṣi fun iṣẹ ti wọn ṣe fun ile-ẹkọ lapapọ ati ẹka eto ẹkọ wọn . Lara wọn lati ri :
1.Oyewọle Aminat – Female Science Star of
the Year .
2.Olugboso Toheeb – Hall of Flame Award
3.Odewale Kehinde – Most Reserved Student of the Year.
4.Isreal Ogunlana – Event Planner ot the Year.
5.Marvleous Adeniyi – Most Beautiful Girl of the Year.
6.Ayuba Kaothar – Humanitarian Personality of the Year.
7.Ogundiran Tosin – Most Punctual Student of the Year.
8.George Blessing – Ebony of the Year.
9.Oluwaniyi Rebecca – Most Punctual Student of the Year

Lara awọn olukọ ti wọn gba amiẹyẹ la ti ri:
1.Dr Saheed Raheem Adetola
2.Dr Bolanle Sotikare
3.Dr Lawal Musliu
4.Dr Oladele Grace
5.Ọgbẹni Adeyẹle Timothy
6.Ọmọwe argbinrin Ọdẹniyi
7.Ọmọwe Adọlabi Akinjide
8.Ọgbẹni Ayọdeji Wright
9.Ọgbẹni Sunday Amọo
10.Ọgbẹni AGC Popoọla
11.Ọgbẹni Seyi Adedeji
12.Ọgbẹni Akinfenwa Damilola
13.Olukọ Kọlapọ Badiru
14.Aarabinrin Modupẹ Christiana Ọkanlawọn

Awọn akẹkọọ miran ti wọn tun gbamiẹyẹ ni:
1.Bolaji Ismaheel – Outstanding Student of Year
2.Akeleke Toheeb – Humanitarian Service Award
3.Tijani Sodiq – Class Representatinve of the Year
4.Oyelẹyẹ Ayọmipọsi – Excellent Academic Award
5.Dada Mariam – lntegrity & Trustworthy Award
6.Babatunde Balogun – Broadcasting & African Researcher of the Year
Oshina Elizabeth – Most Humorous Persality

Oniru-nru awọn olorin takasufe ti wọn tun jẹ ọmọ ‘le-ẹkọ ọun ni wọn tun da awọn eniyan lara ya. Lara wọn lati ri Fela, Beto-Boy ati awọn miran.