Atiku àti NBA ní kí ìjọba gbàgbé owó orí lásìkò yìí

Atiku àti NBA ní kí ìjọba gbàgbé owó orí lásìkò yìí

Yínká Àlàbí

Igbakeji Aarẹ tẹlẹ ri ni orileede yii, Atiku Abubakar ati awọn ajọ Agbẹjọro (NBA) ilẹ wa ti gba ijọba apapọ nimọran to gbopọn bi awọ Erin.
Wọn ni ki ijọba tilẹ kọkọ sọ ọrọ owo ori di afisẹyin ti eegun n fi asọ.
Ajọ NBA ati Atiku ni ebi to wa ninu bayii ju ọrọ owo ori lọ. Wọn ni o yẹ ki ljọba yii le ni aanu ara ilu.
Wọn ni eyi to tilẹ wa ba gbogbo rẹ jẹ ni awọn to tun ti ọwọ aye bọ alaalẹ owo ori naa. Ni eyi to maa mu inira ba ara ilu ju ohun ti o wa ninu alaalẹ lọ.
Wọn tun rọ ijọba apapọ lati fi ọwọ sinkun ofin mu awọn ti aje ibajẹ titọwọ bọ alaalẹ naa ba si mọ lọwọ.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here