Àsírí Ribadu àti Femi Falana – Olunloyo
Nje̩ eleyii wa le je̩ ooto̩ bi? Arabinrin Kemi Olunloyo to ti di aya Lawrence lo n tu bi ejo lori ero̩ ayelujara nipa alaga ajo̩ EFCC laye Aare̩ Olusegun Obasanjo̩ ati agbe̩joro agba, Femi Falana.
B gbo̩ fidio naa funra yin…