Ajá bíbá ní àsepọ̀ ni eré mi àkọ́kọ́ – Nkechi Blessing
Yínká Àlàbí
Gbajú gbajà òsèré orí ìtàgé, arabinrin Nkechi lo n salaye yii fun awọn oniroyin.
O sàlàyé pe eniyan tilẹ n bọ soju agbo sere ni wọ́n fun oun ni eré ibi tí òun àti ajá ti maa ní asepọ.
Oun yaa sa asala fun ẹ̀mí óun, nitori pe ohun tí àwọn ayé ba kọ́kọ́ mọ òuṇ sí lo máa mọ wọn lara.
Nkechi ní bí òun ti kọ abala ere naa sílẹ̀ tí wọn fun òun ní abala miiran ni àwọn kan ti bẹ́ mọọ.
“Mi ò tilẹ̀ gbúròó àwọn ènìyan bẹ́ẹ̀ mọ́ nínú eré”.









