AFCON 2025 : Super Eagles jáwé olúborí bọ́ sí ìpele ẹlẹ́ni mẹ́jọ
Yínká Àlàbí
Super Eagles gbo ewuro si oju ikọ Agbabọọlu Mozambique pẹlu ami ayo mẹrin si odo.
Eyi maa gbe wọn si ipele ẹlẹni mẹjọ.
Orileede Morocco ni idije bọọlu naa ti n waye.
Bẹẹ ni orileede Egypt naa fiya jẹ ikọ toi Benin republic pẹlu ami ayo mẹta si ẹyọkan.










