Ada Jesus sò̩rò̩ lórí è̩sùn ìbálòpò̩ pè̩lú Dino Melaye àti Ashmus tí wó̩n fi kàn án

Ada Jesus sò̩rò̩ lórí è̩sùn ìbálòpò̩ pè̩lú Dino Melaye àti Ashmus tí wó̩n fi kàn án

Mary Fágbohùn

Aderinposonu Naijiria, Nons Miraj ti a mo si Ada Jesus so ooto to wa nidii esun ti won fi kan an pe o ni ibalopo pelu Dino Melaye ati ore re, Ashmusy.

E ranti pe ni ose die seyin, alariyanjiyan onirohin ayelujara kan fi aworan Melaye, agbenuso fun igbimo ipolongo fun oludije ipo aare ninu egbe oselu Peoples Democratic Party (PDP) lede, ti won si fi esun kan n pe o ni ibalopo elenimeta pelu Nons Miraj ati ore re, Ashmusy.

Nons Miraj ninu iforowero kan pelu olootu eto talk show, Chude Jideonwo  ni ojoru, ti so pe oun pa awuyewuye oro  to n lo lori ayelujara ti nitori pe Nedu gba oun nimoran pe ki o pa aheso oro naa ti.

O tesiwaju lati so fun n pe irohin naa je ki oun ni okiki si i.

O wi pe, “Mo n wa ona lati se atunse awon fonran mi ki n si mu oro yi jade. Mo n sise ni, (wi pe) ‘olootu satunse kinni yii, abi ki lo n sele’. Enikan pe mi wi pe, ‘onirohin yi ti gbe o jinna gidi o!’

“Mo pariwo ‘Jesu ’ mo lo wo, leyin naa, mo ri ara mi, pelu Dino ni aarin, mo tun ri ‘ibalopo elenimeta’.

“Leyin naa, mo pe ore mi ko wole,

‘Nonso, ki lo sele?’

Mi o mo bi mo se fe salaye fun iya mi pe iro ni. Bawo lo se fe salaye fun awon eniyan pe o o se nitori pe won o si nibe pelu re.

Ti e ba wa oruko wa lori ayelujara bayi, e o ri atejade emi, Ashmusy ati okunrin to wa laarin. O ma ye yin pe mo fe rin irinajo kuro lorile-ede yi; e ma lo ronu pe asewo ni eleyi o. O je ohun to bi eniyan ninu.

“Awon eniyan n gba mi ni imoran lati ma so nnkankan lori irohin naa. Sugbon nitori pe o dami loju pe mi o mo nkankan, mo fi ateranse ranse si won pe ‘Olorun yoo fiya je yin fun nkan yi, e ma ku ni’. Leyin naa, mo funra mi nigboya, “Nonso, o o se nnkan yi”. Mi o mo onirohin yi, sugbon  enikeni to ba wa leyin eyi, ‘ mu aridaju wa!

Nitori naa, nigba ti eni naa ba fe mu irohin miiran wa, gbogbo awon ore mi wi pe ‘mu aridaju wa o’, ‘Ma lo si irohin miiran, nitori pe o le fi esun kan mi ki awon eniyan le ma a ka irohin re’. Boya oju awe naa ti n ku lo, ti won si gbodo se nkan si ki awon eniyan le mo leekan sii. Mi o feran iru erongba be, sugbon pipariwo eniyan fun rere tabi buburu, ipariwo ni gbogbo re.

“Emi? Mi o ri gege bi afenifere, bi ore mi se so pe oun ri oun si se igbasile re. Ti mo ba ri, ma a lo fa lese ni. Mi o ti ri okunrin yi ri, ooto to wa nibe ni yi.”

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here