Ìjo̩ba àpapò̩ ti ilé-ìwé mó̩kànlélógójì nítorí ààbò

Ìjo̩ba àpapò̩ ti ilé-ìwé mó̩kànlélógójì nítorí ààbò

Yínká Àlàbí

Ijo̩ba apapo̩ ti Naijiria ti awo̩n ile iwe ijo̩ba mo̩kanlelogoji(41) nitori aabo to me̩he̩ ni awo̩n ile̩ Hausa.
Ikilo̩ to gbopo̩n bii awo̩ Erin te̩le as̩e̩ ijo̩ba apapo̩ naa, ijo̩ba kilo̩ fun gbogbo awo̩n olori ile iwe naa pe omimi kankan ko gbo̩do̩ mi alaale̩ ijo̩ba naa.
Hajia Binta Abdulkadir to je̩ dire̩kito̩ Se̩ko̩ndiri agba fun ijo̩ba apapo̩ lo fi iwe naa ranse̩ si gbogbo “Federal Unity Colleges.”
Awo̩n ile iwe naa ni –
Federal Government Girls College (FGGC) Minjibir; Federal Technical College (FTC) Ganduje; FGGC Zaria; FTC Kafanchan; FGGC Bakori; FTC Dayi; FGC Daura; FGGC Tanbuwal; FSC Sokoto; FTC Wurnol FGC Gusau; FGC Anka; FGGC Gwandu; FGC Birnin Yauri; FTC Zuru; ati FGGC Kazaure.
Awo̩n to ku ni FGC Kiyawa; FTC Hadejia; FGGC Bida; FGC New-Bussa; FTC Kuta-Shiroro; Federal Government Academy (FGA) Suleja;
FGC Ilorin; FGGC Omuaran; FTC Gwanara; FGC Ugwolawo; Ara wo̩n ni FGGC Kabba; FTC Ogugu; FGGC Bwari; FGC Rubochi; FGGC Abaji; FGGC Potiskum; FGC Buni Yadi; FTC Gashua; FTC Michika; FGC Ganya; FGC Azare; FTC Misau; FGGC Bajoga; FGC Billiril àti FTC Zambuk.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here