Peter Rufai sùn un re o

Peter Rufai sùn un re o

Yínká Àlàbí

Aisan ranpe̩ lo se adilemu fun iko agbabo̩o̩lu orileede yii, Peter Rufai ti gbogbo aye mo si ‘Dodomayana’ ti o̩lo̩jo̩ fi de ni e̩ni o̩dun mo̩kanlelo̩go̩ta. (1963-2025).
Gbogbo o̩mo̩ Naijiria, a ku ara fe̩ ara ku. Ki Eledua je̩ ki o̩dun o jinna si ar