Are̩gbe̩so̩la, David Mark dalága àti akò̩wé e̩gbé̩ ADC

Are̩gbe̩so̩la, David Mark dalága àti akò̩wé e̩gbé̩ ADC

Yínká Àlàbí

Gomina ipinle̩ Osun te̩le̩, O̩gbe̩ni Rauf Are̩gbe̩so̩la ti di alaga e̩gbe̩ oselu ADC (African Democratic Congress), nigba ti Alagba David Mark di Alaga e̩gbe̩ oselu naa bi o tile̩ je̩ pe fidi-he̩ si ni awo̩n oye naa.
Ninu e̩gbe̩ oselu naa ni a ti ri awo̩n o̩to̩ku ilu bii Atiku Abubakar, Peter Obi, Nasir El-Rufai, Rotimi Amaechi, Dino Melaye, Solomon Dalung, Dele Momodu, Suswam, Ireti Kingibe, Emeka Ihedioha, Air Marshal Sadique Abubakar (retd.) ati be̩e̩ be̩e̩ lo̩.
Gbongan Shehu Musa Yar’Adua ni Abuja ni ipade naa ti waye.