David Mark kò̩wé f’e̩gbé̩ PDP sílè̩
Yínká Àlàbí
Iroyin yajoyajo to jade laipe̩ yii n fidi re̩ mule̩ pe olori ile igbimo̩ asofin agba te̩le̩, alagba David Mark ti ko̩we f’e̩gbe̩ sile̩ bayii. O ni oun ko le maa s’e̩gbe̩ ija loni rogbodiyan lo̩la. O ni ojumo̩ kan ijo̩ngbo̩n kan ni e̩gbe̩ naa. O ni bi oun ko se mo̩ eyi ti awo̩n olori e̩gbe̩ n se ni oun ko mo̩ eyi ti awo̩n o̩mo̩ n se.
Mark ni oun ko si fe̩ ki o di ariyanjiyan pe ara wa ni tabi ara wa ko̩ ni o je̩ ki oun fi iwe see.
Alagba yii ko tii so̩ inu e̩gbe̩ to fe̩ lo̩ darapo̩ mo̩ sugbo̩n o ni oun ko se PDP mo̩.
Bi o ba se n lo̩ iroyin maa je̩ ki a gbo̩.