Ọmọ Igbo ni mí nípa ẹ̀jẹ̀ – Davido

Ọmọ Igbo ni mí nípa ẹ̀jẹ̀ – Davido

Mary Fágbohùn

Akọrin Afrobeats, David Adeleke, ti gbogbo eniyan mọ si Davido, ti sọ pe ọmọ Igbo ni oun nipa ẹjẹ.

Olórin náà sọ èyí lásìkò tó ń fèsì sí oro eni kan tó kìlọ̀ fún un nípa àjọṣe re pẹ̀lú àwọn ọmọ Igbo.

Eni naa se’kilo wi pe awon omo Igbo le dale re, nitori pe omo Yoruba ni.

Olumulo X, Yakbel kowe, “Davido kan n gbe Ibo si gbogbo ara, titi di igba ti won a dale re ko to sinmi, omo Yoruba to n kowo pelu awon Ibo ni 2025, won fe ori ati ohun gbogbo ti o ni lati je ti won. O ko le tẹ awon Ibo lọrun lailai.

Sugbon, nigba to n fesi, Davido so pe Igbo ni oun funra oun.

O kowe, “Mo rerin. Igbo nipa eje ni mi.