O̩te̩do̩la f’o̩kò̩ ojú omi ńlá se o̩jó̩ò̩bí
Yínká Àlàbí
Yoruba bo̩, wo̩n ni, e̩ni nla lo n se nnkan nla.. eyi lo difa fun Bo̩ro̩kinni onisowo n ni.
Oni ni baba olowo yii pe O̩go̩ta o̩dun. O sii woo pe kin ni ohun ti enikan ko tii se ri ni eyi to mu ki baba naa lo gba o̩ko̩ oju omi olowo nla kan ti wo̩n n pe ni ‘yatch’.
O̩te̩do̩la ti gbogbo eniyan mo̩ si Bilio̩nia lo gba o̩ko̩ naa ni owo to le ni bilionu meji naira.