Adẹ́rìn-ín-pòsónú AY fèsì sí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án lórí ọ̀nà tí ó ń gbà t’ọ́mọ

Adẹ́rìn-ín-pòsónú AY fèsì sí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án lórí ọ̀nà tí ó ń gbà t’ọ́mọ

 

Mary Fágbohùn

 

Aderin-in-posonu ati agberejade Ayo Makun aka AY ti fesi si oro awon kan ti won n pe e ni eni to n si omo lo. 

 

Alawada naa, leyin ti ina sun ile re to wa ni Eko ni ojo die seyin, sese ko lo si United States fi fonran omo re odun kan lede nibi to ti n nu ile.

 

Osere naa fikun un pe oju opo ipe Child Help National Child Abuse ko si ni Atlanta.

 

O so fun awon ti won n da a lebi naa pe ki won gbajumo oro aye won tabi ki oun ran ina to sun ile oun si ile ti won naa.

 

“Oju opo Ajo to n ran omo ti a silo lowo ni orile ede (ChildHelp National Child Abuse Hotline) ko si ni Atlanta. E gbajumo oro aye yin tabi ki n ran ina to jo ile mi si ile yin. E je ki aderin-in-posonu yi MI EEMI,” ni o so.

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here