Burna Boy sò̩rò̩ lórí aye̩ye̩ ìgbéyàwó Yhemo Lee
Olorin takasufe Burna Boy ti so erongba re lori igbeyawo Naijiria.
Olorin African Giant naa so ero re nigba to n soro lori ayeye Yhemo Lee ti won ti file poti, ti won si fona roka.
Nigba to fi aworan Yhemo Lee ati iyawo re lede lori itan Instagram, o ko o pe, “Igbeyawo Naijiria dara ti won ba se ni ona ti o to!”
Iroyin jade pe Yhemo Lee se idana pelu, Thayour, ni Eko ni ojo Abameta, ogbonjo osu kejo, 2024.