Wó̩n lò mí fùn Tinubu ni’ – Portable

Wó̩n lò mí fùn Tinubu ni’ – Portable

Alariiyanjiyan olorin, Habeeb Okikiola, ti a mo si Portable, ti figbe ta pe oun ko gba ebun owo kankan bi o tile je wi pe oun se atileyin fun Aare Bola Tinubu.

Gege bi o se so, won “lo o ni” sugbon o ni suuru.

Nigba to n soro pelu awon afenifere re lori Instagram, olorin ‘Zazu’ naa wi pe biba ijoba “ja” je ise ti ko lere, o ni ijoba ko ni nnkankan lati padanu.

O wi pe: “Mo satileyin fun Tinubu sugbon mi o ri owo kankan. Mo ni suuru.E n pa ara yin lori pe e n ba ijoba ja ni. Ijoba ko ni nnkankan lati padanu.”

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here