Ilé E̩lé̩gbò̩n-ó̩n Àgbà Naijiria abala ke̩sàn-án: ‘Ìbásepò̩ mi tó pé̩ jù ni osù mé̩rin’ – Victoria
Omole Elegbon Agba Naijiria abala kesan-an, Victoria so nipa ibasepo ife ti o je olojo pipe ti o ni iriri re.
Omole naa ni abala ibeere ati idahun ni ojo Isegun so eyi di mimo.
Enikeji re Shaun safihan pe ibasepo ti oun ni ti o pe ju ni odun meji si meta.
Amo sa, Victoria si iyalenu so pe ti oun ko tile pe odun merin.
Oluforo-wani-lenu-wo : “Bawo ni ibasepo ti o ni se pe to si?”
Victoria: “Bii osu merin.”
Iroyin jade pe Victoria ko jara mo eto naa lati ibere, eyi to n pa ibasepo pelu enikeji re ati awon omole miran lara.
Enikeji re, Shaun sawawi kikan ni ojo Aiku nitori aibanisoro re.