O̩kùnrin tí a jo̩ gorí ara wa lé ni 3000 – Òsèré tíátà, Esther Nwachukwu
Mary Fágbohùn
Alariiyanjiyan osere tiata Esther Nwachukwu, ti a mo si Esther Sky, ti so ohun iyalenu nipa igbe aye ibalopo re.
Osere naa safihan pe oun ko le ka iye okunrin ti oun ti ni ibalopo pelu.
O so eyi laipe yi lori eto ‘The Honest Bunch’ ti oun ati osere tiata Chinedu Ani Emmanuel, ti a mo si Nedu, Husband Material, Deity Cole ati Ezinne jo se atokun re.
Nedu beere pe: “Eniyan meloo ni o ti ni ibalopo pelu?”
Nwachukwu dahun pe: “Mi o le ka won.”
Nedu: “Se o to egberun kan?”
Nwachukwu: “O ju bee. Mo pe omo ogbon odun ni ojo keje osu keje.”
Nedu: “Bii meloo ni awon okunrin ti o ti ni ibalopo pelu yoo to.”
Nwachukwu: “Mi o le ka iye okunrin ti mo ti ni ibalopo pelu. Mi o tile ranti.”
Nedu: “Se o to egbeeedogun?”
Nwachukwu: “O ju be. Mo ti ni ibalopo pelu okunrin lati Naijiria , Cyprus, Turkey, Kenya, Ghana, ati bee bee lo. Mi o kii n ni ibalopo pelu okunrin ti ko ti ni iyawo, awon to ti ni iyawo ni mo maa n ba lopo.