Burna Boy dá iléèwé agbábó̩ò̩lù sílè̩ ní Eko

Burna Boy dá iléèwé agbábó̩ò̩lù sílè̩ ní Eko [FONRAN]

Irawo olorin, Burna Boy ti da ile iwe agbaboolu sile ni ipinle Eko.

Ile iwe naa (The Burna Boy Football Academy) ni irohin jade pe yoo maa sise ni ojo meta laarin ose, pelu wakati meji fun ikekoo.

Ninu fonran to n lo kaakiri lori ayelujara, a ri awon odomode agbaboolu ti won n kekoo labe idari olukoni.

Gege bi oju awe ile-iwe naa se, ipilese re ni lati saajo awon to feran boolu gbigba ti ojo ori won wa laarin odun merin si merindinlogbon: oje wewe ati awon agba ti wa laarin odun merindinlogun si mokanlelogun.

 

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here