Màá wà pẹ̀lú rẹ titi láí– Portable se ìlérí títí ayé fún Queen Dami

Màá wà pẹ̀lú rẹ titi láí– Portable se ìlérí títí ayé fún Queen Dami

 

Alariyanjiyan olorin Naijiria, Portable, ti se ileri titi lai fun ọrẹbinrin rẹ, queen Dami.

Portable so eyi ni ọjọ Aje nigba to n sajọyọ ọjọ ibi queen Dami.

Nigba to fi aworan queen naa lede ninu ifilede kan lori Sítágíràmù, ònkọrin naa seleri lati wa pẹlu rẹ titi lai.

“Ku oriire ọjọ ibi Mummy Ọba. Olori Onirawọ mi. Alayọ, maa wa pẹlu rẹ titi lai. Ọlọrun yoo bukun ọjọ ori rẹ tuntun. @officialqueen_dami.”

Ẹ ó ranti pe Portable ni osu kẹjọ ọdun 2023, ti fi idi ibasepọ rẹ pẹlu Queen Dami mule, olori Alaafin Ọyọ tẹlẹri.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here