Ṣọlá Sobowale ṣàjọyọ̀ ọjọ́ ìbí àwọn ìbeji rẹ̀

Ṣọlá Sobowale ṣàjọyọ̀ ọjọ́ ìbí àwọn ìbeji rẹ̀

Òsèré tíátà, Sola Sobowale, n sàjọyọ̀ ọjọ́ ìbí àwọn ọmọbìnrin ìbejì rẹ̀.

Ninu atẹjade kan to fani lọkan mọra lori Sítágíráàmù, Sobowale safihan ìfẹ́ rẹ̀ ati ìmoore rẹ̀ si Ọlọ́run fun ẹ̀bun nla ti o ri gba.

O kọ ọ́ pé: “Ibeji mi! Awọn ọmọbinrin mi. Loni mo n ki yin ku oriire ọjọ ibi ẹ̀yin èjìrẹ́ mi ọ̀ wọ́n. Oluwa bukun mi pẹ̀lu ẹ̀bun yin ti o rewa ti o si se iyebiye. Oluwa yoo pa yin mọ yoo si wa pẹ̀lú yin. Gbogbo nkan ti e ba dawole yoo se rere. Mo fe e yin fe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ninu ayọ̀, alaafia, ati aseyọri. Ọlọ́run yoo bukun yin, ẹ̀yin olufẹ́ mi. Iya yin fẹ́ran yin”.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here