Gbajúgbajà olórin, Vector Tha Viper pàrọwà sáwọn èèkàn ìlú láti
kọjú ò̩rò̩ síjọba kanjú ko

Mary Fágbohùn

Iroyin jade pe ni bii ọdun diẹ sẹyin, pupọ ninu awọn ilumọọka Naijiria ti darapọ mọ eto oselu tabi ki wọn kede atilẹyin wọn fun awọn oloselu.
Nigba ti o n fesi si eyi, Vector bu ẹnu atẹ lu awọn ilumọọka ti wọn n gbè lẹyin awọn oloselu tako okodoro ohun ti awọn eniyan rere ilu n koju.

O se’kilọ pe bi nnkan se le yi yoo kan awọn naa ti wọn ko ba dawọ rẹ duro.

Ni oju awe X rẹ, Vector kọ ọ pe: “Si awọn ilumọọka ti wọn n gbe lẹyin awọn oloselu lodi si okodoro ọrọ awọn eniyan/afenifere won, o le jẹ ohun to dara lati ronupiwada saaju ki e to di aayo ti yoo kan ti ohun to le koko yi ko ba dawo duro. E jawọ ninu sise atilẹyin eto isejoba ti ko dara.”

Imọran rẹ yi losi ohun ti ifehunu han kaakiri orilẹ ede to n lowo lori bi nnkan ko dẹrun yi duro le lori.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here