Ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ìbò ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, àwọn olùdíje wọ̀nyí fẹ́ ẹ́ jókòó lórí àga kan ṣoṣo
Ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ìbò ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, àwọn olùdíje wọ̀nyí fẹ́ ẹ́ jókòó lórí àga kan ṣoṣo
Fẹ́mi Akínṣọlá
Ètò ìdìbò Èkìtì gbéra sọ lọ́jọ́ Àbáamẹ́ta, ọjọ́ kejìdínlógún, Oṣù kẹfà, ọdún 2022.
Enikẹ́ni tó bá borí nínú ètò ìdìbò yìí ni yóó gbégbá orókè. tí yóó sì di gómìnà kẹjọ tí yóó ṣàkóso ìpínlẹ̀ ọ̀hún.
Àjọ elétò ìdìbò Orílẹ̀ yìí, Independent Electoral Commission, INEC ni yóó ṣètò ìdìbò náà.
Láti ìgbà tí ìṣèjọba àwaarawa ti bẹ̀rẹ̀ ní Èkìtì ,kò tí ì sí ẹgbẹ́ òṣèlú kan náà tó gbé ìjọba kalẹ̀ fún ọmọ ẹgbẹ́ ẹ wọn kan náà rí.
Oyebanji (APC); Kolawole (PDP), Oni (SDP) àti Ajayi (YPP)ni olùdíje mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó ń dáfun tòló láti gorí àpèrè sípò o Gómìnà ní ìpínlẹ̀ ọ̀hún.
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…