Home ÀKỌ̀TUN Ìdìbò kó se’bẹ̀’ wáyé ní ìlú Ado – Segun Oni figbeta
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - 1 week ago

Ìdìbò kó se’bẹ̀’ wáyé ní ìlú Ado – Segun Oni figbeta

Dìbò kó se’bẹ̀’ wáyé ní ìlú Ado – Segun Oni figbeta

Ọrẹ Òtítọ́jù

Olùdíje lẹ́gbẹ́ òṣèlú Social Democratic Party, SDP , Segun Oni ti ké gbàjarè pé àwọn kan ra ìbò àwọn olùdìbò ní ìdìbò sípò gómìnà tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkìtì.

Oludije naa sọ eyi lasiko to lọ di ibo rẹ ibudo idibo rẹ ni nkan bii aago mẹwaa owurọ.

Bakan naa lo fikun un pe agbegbe Ado-Ekiti ati Oye-Ekiti ni wọn ti n ra ibo awọn eniyan.

‘’Awọn eniyan mi ti fi to mi leti pe awọn kan n ta ibo ra-ibo ni agbegbe Ado ati Oye. Eleyii tako ofin orilẹede Naijiria.’’

‘’Mo n kesi awọn agbofinro ki wọn lọ ṣiṣẹ wọn bii iṣẹ kiakia, ki wọn fopin si nkan to n waye nibẹ’’.

Nibayii, ti esi idibo ti n wọle ni iroyin gbe e pe Segun Oni ti bori ni ẹkun idibo rẹ.

Saaju ni iroyin tun fi sita pe ẹrọ idibo kọ iṣẹ silẹ ni ibudo idibo naa ko to dipe o tun bẹrẹ si ni ṣiṣẹ pada.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…